Fágbáyímú

Sísọ síta



Ìtumọọ Fágbáyímú

Ifá has taken a hold (of this child).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-gbá...mú-èyí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, corpus, brotherhood
gbá...mú - grab onto, hold onto
èyí - this (one)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
AKURE



Irúurú

Ifágbáyímú