Fádámilá

Sísọ síta



Ìtumọọ Fádámilá

A shortening of Fádámiláre, Ifá provided me with vindication.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ifá-dá-mi-ní-àre



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination, worship, priesthood, corpus
- select
mi - me, my
- have, own; in
àre - justification


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI



Irúurú

Fádámiláre

Ifádámiláre