Sísọ síta
Ifá has returned home.
(i)fá-bọ̀-wá-ilé
Ó pọ̀ ní: GENERAL
Bọ̀wálé
Wálé
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.