Fábùsíwà
Sísọ síta
Ìtumọọ Fábùsíwà
1. Ifá added to our good character 2. A variant of Fábùsúà, Ifá has added to our gathering/celebration
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-bù-sí-ìwà, ifá-bù-sí-ùà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination/corpus/priesthoodbù - to add to, to scoop
sí - at; to, into
ìwà - character
ùà - the society, a gathering, celebration
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI
ONDO