Fáọlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Fáọlá
1. Ifá of honor. 2. A variant of Ifáwọlá - Ifá has entered honor.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ifá-ọlá, ifá-wọ-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ifá - Ifá divination, priesthood, corpusọlá - wealth/nobility/success/honor
wọ - enter
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI