Eyínfúnjowó
Sísọ síta
Ìtumọọ Eyínfúnjowó
(One with) teeth whiter than (cowrie) money.
Àwọn àlàyé mìíràn
An alias.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
eyín-fún-ju-owó
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
eyín - teethfún - white (funfun)
jù - more than
owó - money
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL