Ewétúgà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ewétúgà

Medicine is worth royalty.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ewé-tó-ugà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ewé - herbs, leaves, medicine
tó - suffice for
ugà - throne room


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
OGUN