Elúsọjí

Sísọ síta



Ìtumọọ Elúsọjí

The slave arose.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

elú-sọjí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

elú - slave (ẹrú)
sọjí - arise


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IFE