Elújọbí
Sísọ síta
Ìtumọọ Elújọbí
The Elú has joined in the birth of this child.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
elú-jọ-bí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
elú - an ancient Ife chieftaincy title; a class of Ife chiefsjọ - together, in collaboration
bí - to give birth to
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IFE