Elúfowójù
Sísọ síta
Ìtumọọ Elúfowójù
The slave, because of riches, is great(er).
Àwọn àlàyé mìíràn
"Altogether it sounds rather arrogant, however when I pressed my dad several years ago with the same question he said our name simply means 'The Slave that rose from rags to riches'" - Femi Elúfowójù Jnr, actor-director and radio producer.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
elú-fi-owó-jù
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
elú/ẹrú - slavefi - use
owó - money, wealth, riches
jù - exceed(ing), greater than, bigger than, more than
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Femi Elúfowójù Jnr
actor-director and radio producer.