Elúshadé

Sísọ síta



Ìtumọọ Elúshadé

The Elú title is royal.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

elú-ṣe-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

elú - an ancient Ife chieftaincy title; a class of Ifẹ̀ chiefs
ṣe - make
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IFE



Irúurú

Elúṣadé