Eléghóbọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Eléghóbọ́lá

A variant of Olówóbọ́lá, the rich person has met honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

oní-eghó-bá-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

oní - one who owns; has
eghó - money, cowries (owó, oghó, eó, ió)
- meet, join
ọlá - honour, prestige, wealth, nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OWO