Egúntọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Egúntọ́lá

The masquerade is worth wealth.



Àwọn àlàyé mìíràn

NOTE ON ORTHOGRAPHY The proper way to write this name should be "Eégúntọlá" in order to allow for all the tone marks to be properly accounted for. However, most modern versions lose the first vowel, for ease of Anglophone writing, perhaps.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

eégún-tó-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

eégún - masquerade
tó - match, suffice for, is big enough for
ọlá - wealth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Tọ́lá