Eégunjọbíẹ

Sísọ síta



Ìtumọọ Eégunjọbíẹ

The masquerade jointly gave birth to this.



Àwọn àlàyé mìíràn

Nombre religioso. Name commonly given in Latin America. A corruption of Eégúnjọbí.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

eégún-jọ-bí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

eégún - masquerade
jọ - in collaboration
bí - give birth to


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IFE



Irúurú

Eégúnjọbí

Égúnjọbí