Égúnyẹ́mí

Sísọ síta



Ìtumọọ Égúnyẹ́mí

Being a masquerader befits me.



Àwọn àlàyé mìíràn

Proper spelling: Eégúnyẹmí .



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

eégún-yẹ-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

eégún - masquerade (elégún)
yẹ - befit
mí - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Yẹmí

Eégúnyẹmí