Èyítófọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Èyítófọ́lá

A child enough for wealth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

èyí-tó-fún-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

èyì - this (one)
tó - be sufficient
fún - for
ọlá - wealth, success, nobility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Tófọ́lá