Èyíówùáwí
Sísọ síta
Ìtumọọ Èyíówùáwí
We do not wish to say this.
Àwọn àlàyé mìíràn
The full saying goes "Èyí ó wù á wí, t'Olúwa l'àṣẹ.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
èyí-(tí)-ó-wù-kí-á-wí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
èyí - this, whattí ó - that
wù - like, love, prefer
kí - that
a - we
wí - say
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL