Èṣùtúndé

Sísọ síta



Ìtumọọ Èṣùtúndé

Èṣù has returned.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

èṣù-tún-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

èṣù - Èṣù, the deity of consequence, messengers, trickery
tún - again
- arrive, return


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Túndé