Èṣùkẹ́mi

Sísọ síta



Ìtumọọ Èṣùkẹ́mi

Èṣù cares for me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

èṣù-kẹ́-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

èṣù - Èṣù, the Yorùbá trickster god
kẹ́ - cares for, dotes on
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
FOREIGN-GENERAL
GENERAL



Irúurú

Kẹ́mi