Èṣúgbèmí
Sísọ síta
Ìtumọọ Èṣúgbèmí
Èṣù (worship) is beneficial to me.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Olúgbèmí, Adégbèmí, etc.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
èṣù-gbè-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
èṣù - Èṣù, the Yorùbá trickster deitygbè - support
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL