Èṣúbùnmi
Sísọ síta
Ìtumọọ Èṣúbùnmi
Èṣù gave me (this child).
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Olubùnmi
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
èṣù-bùn-mi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
èṣù - the deity Èṣubùn - gift
mi - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL