Dúródolú

Sísọ síta



Ìtumọọ Dúródolú

Wait for God.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

dúró-de-olú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

dúró - wait, stop, stand
dè - for
olú - lord, prominent one, olúwa


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dúró

Dolú

Dúródolúwa