Dúrówojú

Sísọ síta



Ìtumọọ Dúrówojú

Wait long enough to behold faces.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

dúró-wo-ojú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

dúró - wait, stop, stand
wò - look, stare, behold
ojú - face, eyes


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Irúurú

Dúró