Dúróshọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Dúróshọlá

Wait and make wealth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

dúró-ṣe-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

dúró - wait
ṣe - make
ọlá - wealth, affluence, notability


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dúróṣọlá

Dúró

Ṣọlá