Dúrókifá

Sísọ síta



Ìtumọọ Dúrókifá

Wait around to praise Ifá.



Àwọn àlàyé mìíràn

An àbíkú name. See also: Dúrótifá



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

dúró-ki-ifá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

dúró - wait, stay
ki - strong, thick
ifá - Ifá divination, priesthood, corpus


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IFE



Irúurú

Rókifá