Dúrójaiyéọba

Sísọ síta



Ìtumọọ Dúrójaiyéọba

Wait to enjoy the life of a king.



Àwọn àlàyé mìíràn

This is likely an àbíkú name given to encourage the child to stay and not die.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

dúró-jẹ-ayé-ọba



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

dúró - wait, stay
jẹ - eat, enjoy
aiyé - life
ọba - king


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
YAGBA



Irúurú

Dúrójayé

Dúrójayéọba