Doyinmọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Doyinmọ́lá

Add sweetness to honour



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

da-oyin-mọ́-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

da - pour
oyin - honey, sweetness
mọ́ - add to
ọlá - wealth, nobility, success, prestige, honour


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Irúurú

Doyinsọ́lá