Dénlóyè
Sísọ síta
Ìtumọọ Dénlóyè
1. Cover me with honour. 2. My crown has honour.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
dé-mi-ní-oyè, (a)dé-mi-ní-oyè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
dé - cover, crown [verb]mi - me
ní - with
oyè - honour, title, chieftaincy
-
adé - crown [noun]
mi - me
ní - to have
oyè - honour, title, chieftaincy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IFE