Sísọ síta
The crown gave me to cherish.
(a)dé-fún-mi-kẹ́
Ó pọ̀ ní: GENERAL
Adéfúnkẹ́
Fúnkẹ́
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.