Déṣíkù
Sísọ síta
Ìtumọọ Déṣíkù
The crown opens a door (of wealth to me).
Àwọn àlàyé mìíràn
The name is from Usi Èkìtì.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
(a)dé-ṣí-ikù
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crownṣí - open
ikù - door (ilẹ̀kùn)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI