Darálèṣù
Sísọ síta
Ìtumọọ Darálèṣù
Èṣù is one who becomes like kin (shortening of Adarálèṣù).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
di-ará-ni-èṣù
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
di - becameará - kin, family, relations, kith
ni - is
èṣù - Èṣù, the deity of consequence, messengers, trickery
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL