Dánlọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Dánlọ́lá

Bless me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

dá-n-ní-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

dá...lọ́lá - bless
n - me (mi)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dámilọ́lá