Dáyìsí

Sísọ síta



Ìtumọọ Dáyìsí

(Death) Spared this.



Àwọn àlàyé mìíràn

This is an abíkú name.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(ikú)-dá-èyí-sí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ikú - death
dá...sí - spare
èyí - this (one)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dáìsí

Ikúdáìsí

Ikúdáyìsí

Kúdáìsí