Dáminí

Sísọ síta



Ìtumọọ Dáminí

Hold (onto) me.



Àwọn àlàyé mìíràn

See: Olúwadáminí



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

dá-mi-ní



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

dá...ní - alone
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
FOREIGN-GENERAL



Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

  • Dáminí Ogulu also known as Burna Boy. Nigerian musician.



Irúurú

Olúwadáminí