Dáìsí

Sísọ síta



Ìtumọọ Dáìsí

(Death) spared this.



Àwọn àlàyé mìíràn

This is a name given to an àbíkú child.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

dá-ẹ̀yí-sí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

dá...sí - spare
èyí - this (one)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ikúdáyìsí

Ikúdáyìsí

Olúdáìsí

Dáyìsí