Dáṣàólú

Sísọ síta



Ìtumọọ Dáṣàólú

Make beauty for the prominent one.



Àwọn àlàyé mìíràn

[verification needed]



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

dá-àṣà-(fún)-olú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

dá - make, create
àṣà - culture, creativity, artistry
fún - for
olú - prominent one, chief, olúwa


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA