Dípẹ̀sóyè
Sísọ síta
Ìtumọọ Dípẹ̀sóyè
Compensate us into chieftaincy.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
dípẹ̀-sí-oyè
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
dípẹ̀ - replace, recompense, repaymentsí - to
oyè - honour, respect, chieftaincy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO