Díẹ̀kọ́loreolúwa

Sísọ síta



Ìtumọọ Díẹ̀kọ́loreolúwa

The blessings of God are not small.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

díẹ̀-kọ́-ni-ore-olúwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

díẹ̀ - little, small
kọ́ - not
ni - is
ore - goodness
olúwa - lord, God


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL