Díẹ̀kọ́layọ̀mi

Sísọ síta



Ìtumọọ Díẹ̀kọ́layọ̀mi

My joy is not small.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

díẹ̀-kọ́-ni-ayọ̀-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

díẹ̀ - little, small
kọ́ - not
ni - is
ayọ̀ - joy
mi - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ILESHA