Dédénínúọlá
Sísọ síta
Ìtumọọ Dédénínúọlá
A shortening of Adédénínúọlá, The crown has arrived into honor. [verification needed]
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-dé-nínú-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crowndé - arrive, return
nínú - inside
ọlá - honour, wealth, success, notability
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Òṣémàwé of Oǹdó
Ọba Dédénínúọlá (r. 1896-1901)