Dámisọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Dámisọ́lá

Created me into wealth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

dá-mi-sí-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

dá - created
mi - me
sí - into
ọlá - wealth