Bolúwatitó
Sísọ síta
Ìtumọọ Bolúwatitó
(Look at) How great as God is.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Bọ́látitó
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
bí-olúwa-ti-tó
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
bí - likeolúwa - lord, God
ti - has
tó - appear (in size)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA
AKURE
OGUN
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Bólúwatitó Babalọlá (Bolu Babalola): Author of London and New York best seller
'Love in Colour'.