Bólúwatifẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Bólúwatifẹ́

As the lord wants. As God pleases.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bí-olúwa-ti-fẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bí - as, like
olúwa - lord, God
ti - has
fẹ́ - love, want


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Bólútifẹ́

Bólú