Bólúwatiwí

Sísọ síta



Ìtumọọ Bólúwatiwí

As the Lord has said.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bí-olúwa-ti-wí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bí - as
olúwa - lord, God
ti - has
wí - said


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL