Bólúmọlé
Sísọ síta
Ìtumọọ Bólúmọlé
1. Build a bouse with God. Build a house with the prominent one. Build a house with the master. 2. Go with God/Prominent one/master, to know the house.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
bá-ọlú-mọ-ilé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
bá - together with, helpolú - lord, God, prominent one
mọ - build, mould,
mọ̀ - know, recognize, visit
ilé - house, home
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL