Bólújí

Sísọ síta



Ìtumọọ Bólújí

1. Wakes up with prominence. 2. Wakes up with God.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Bọ́lájí



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bá-olú-jí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bá - together with
olú - lord, God, olúwa, the prominent one, prominence
jí - wake up, arise


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Bólú

Bólúwají