Bólódeòkú
Sísọ síta
Ìtumọọ Bólódeòkú
If the owner of the house isn't dead...(his house won't grow weeds).
Àwọn àlàyé mìíràn
The full Yorùbá proverb says "B'ólóde ò kú, òde ò wu gbẹ́gi."
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
bí-olóde-(k)ò-kú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
bí - ifolóde - the owner of the yard/house
kò - does not
kú - die
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL