Sísọ síta
As the lord wishes.
bí-olúwa-ti-fẹ́
Ó pọ̀ ní: GENERAL
Bólúwatifẹ́
Bólú
Tifẹ́
Bóyá o tiẹ̀ ní ìtàn kan láti sọ fún wa nípa orúkọ yìí, tàbí fún wa ní ǹkan tí a ṣì kọ, tàbí fikún oun kan tí a kọ sílẹ̀.