Bíòbákú

Sísọ síta



Ìtumọọ Bíòbákú

If s/he doesn’t die.



Àwọn àlàyé mìíràn

This is a name for àbíkú children, betting on the possibility of their survival.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bí-kò-bá-kú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bí - if
kò - he/she does not
bá - [the act of]
kú - die


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Irúurú

Bíòkú