Bísúgà

Sísọ síta



Ìtumọọ Bísúgà

Born into royalty.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

bí-sí-ugà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

bí - give birth to
sí - into
ugà - throne (igà)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OGUN



Irúurú

Abísúgà.